Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Oriire nla wọle o

Awọn agunbanirọ ati araalu mọkanlelogun ti awọn agbebọn jigbe ni Kogi gba itusilẹ

Ileeṣẹ ọlọpaa sọ pe akojọpọ awọn oṣiṣẹ eleto aabo

lo ṣokunfa bi wọn ṣe gba awọn eeyan naa silẹ ninu igbo kijikiji

Ki wa ni Aarẹ Tinubu sọ lori eyi?

Sare lọ soju opo BBC.CM/Yoruba bi o ba fẹẹ mọ

***********************************************************************************

Ọrẹ mi, ẹru n ba mi o

Ki lo n ba ẹ lẹru

Mo gbọ pe Opay fẹẹ kogba wọle

Rara o, awọn alakoso Opay ti sọrọ

Wọn ni irọ to jinna si otitọ ni, nitori pe awọn ti mọ ẹni to wa nidi iroyin ẹlẹjẹ naa

Opay fidi rẹ mulẹ pe digbi lawọn duro, ati pe...

***********************************************************************************

Miliọnu marundinlọgbọn ti Taiwo Hassan Ogogo gbe fun mi kii ṣe lati fi kọ mọṣalaṣi o

Imaamu agba Ilaro lo sọ bẹẹ nibi eto adura ọjọ kẹjọ ti wọn ṣe fun Ogogo

O sọ pe owo ọhun ni Ogogo ni ki wọn fi pari ile mọlẹbi ko too jade laye

Owo ọhun wa n kọ bayii?