Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Jide Kosoko sọ̀rọ̀ lórí gbèse N300m náírà tó jẹ lórí fíìmù tó gbé lọ sinimá
Ogbontarigi oṣere naa sọ pe gbese owo to le ni miliọnu lọna oọdunrun (N300m) naira toun fi ya iṣẹ naa, loun jẹ lori fiimu tuntun ọhun.
Wó kókó ohun márùn-ún tó yẹ kí o mọ̀ nípa ètò ìpolongo ìbò tí Ààrẹ Tinubu bẹ̀rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kaduna
Fun idi eyi, ki lo de to jẹ pe ipinlẹ Kaduna ni eto ipolongo naa ti bẹrẹ? Ki ni awọn ohun to ṣee ṣe ko jẹyọ nibẹ, ati pe ki lo de ti APC fi yan ipinlẹ Kaduna laayo lati fi ṣide eto ipolongo wọn?
Balogun Ogbomoso: Kí ló ń fa gbas gbos láàárín Soun Ogbomoso àti ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo?
Atẹjade ti Kọmiṣanna fọrọ ijọba ibilẹ ati ọrọ oye ni ipinlẹ Oyo, Ademola Ojo sọ pe gomina nikan lo ni aṣẹ lati yọ oloye to ba wa ni ipo giga bii ti Balogun naa nipo, pe Soun ko ni aṣẹ kankan lati rọ oloye naa nipo rẹ.
Ọlọ́pàá nawọ́ gán èèyàn 135 bí ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn ṣe ń tẹ̀síwájú ní France
Awọn ọlọpaa ni Bordeaux, guusu France sọ pe niṣe ni awọn oluwọde kan n ju awọn nnkan oloro sawọn ọlọpaa, ti wọn si n ṣe ikọlu sawọn ẹṣọ aabo.
Wàhálà yóò ṣẹlẹ̀ bí Gómìná kankan bá rọ Olubadan lóyè - Sunday Igboho fọnmú
Igboho sọ pe digbi loun duro lẹyin Ọba Olubadan, toun si ṣetan lati gbeja rẹ, nigbakugba ti wahala kankan ba fẹẹ dide sii.
Fídíò, Níbo Layé Kọjú Sí?: Kí lobìnrin ń fẹ́ lára ọkùnrin gan? Eyiyemi Afolayan dá sí ìbéèrè yí, Duration 1,59
Eyiyẹmi ọmọ gbajumọ elere itage ni Afọlayan tọka si ifẹ ati nnkan kan, gẹgẹbi ohun ti oun n fẹ lara Ọkunrin.
Àwọn bandiiti ṣìrìn, aráàlú fárígá, pa agbébọn 30
Ohun ti BBC gbọ ni pe awọn eeyan abule naa koju awọn agbebọn ọhun nigba ti ikọlu ojoojumọ su wọn.
Fídíò, 'Ọ̀pọ̀ ìdẹ́yẹsí làwa tí 'polio' sọ di àkàndá máa ń kojú, àmọ́ àwa náà lè dá sí ìdàgbàsókè ìlú', Duration 2,18
Àìsàn rọmọlápá rọmọlẹ́sẹ̀, polio, jẹ́ èyí tí kòkòrò àìfojúrí, poliovirus máa ń fà. Ó máa ń tàn látara ìgbẹ́ ẹni tó bá ni tàbí tí itọ́ ẹni tó bá ni bá kan èèyàn llára.
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nipa Shamonda, kòkòrò àrún tó ṣẹ́yọ́ ní Nàìjíríà, tó ti gbẹ̀mí èèyàn kan ní France
Arun yii ko mu eeyan ri ninu itan, eyi ni igba akọkọ ti iroyin pe o mu eeyan yoo gbode.
Kí ló ṣẹlẹ̀ tí Tope Alabi lóun yóò gba kóòtù lọ? Àlàyé rèé
Ohun ti Tope Alabi n sọ ni pe oun yoo gbe ẹni to ba gbe iroyin irọ nipa oun lọ sile ẹjọ, abi ti ibanilorukọjẹ.
Aráàlú gbé okú gènde márùn-un tó kú sómi lọ sílé ìjọba fún ìdájọ́ òdodo
Iṣẹlẹ yii waye l'Ọjọbọ, ọjọ kejilelogun oṣu Kẹwaa ọdun 2026.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ikéde ìjọba láti mú ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ wálẹ̀ láàárín àádọ́rùn ún ójọ́
Laari aadọrun ọjọ naa ni wọn ni nnkan yoo dẹrun nipa bi ọwọngogo ounjẹ ati owo ọkọ yoo ṣe walẹ.
Fídíò, 'Mi ò rò péToluwanisings lè kú lọ́gbọ̀n ọdún sí àsìkò yìí ṣùgbọ́n...' - Àwọn ọ̀rẹ́ ìpìlẹ̀ Toluwanisings ṣàlàyé àwọn ohun tó ń pinnu kí ikú tó dé, Duration 2,05
O ni awọn ayẹyẹ to ni lọkan fun ọdun 2027 lati ṣe lo yẹ ki awọn maa ṣeto rẹ lọwọ, amọ ayẹyẹ idagbere lawọn wa n ṣe bayii.
'Bí mo ṣe kó Ebola ní Nàìjíríà' - Arákùnrin tí orí kó yọ lọ́wọ́ Ebola ṣàlàyé ohun tójú rẹ̀ rí
Inu oyun ni iyawo naa wa lasiko to lugbadi Ebola to si jade laye.
Ìgbà èwé Toluwanisings le, ọkadà bàbá rẹ̀ ló fi ń gbérò láti rí owó jẹun, ó tún ṣe lébìrà kó tó lu àlùyọ - Ọ̀rẹ́ tímọ́ olóògbé
Nibi eto abẹla titan tawọn eeyan naa se fun oloogbe yii, ni wọn ti kọ oniruuru orin onigbagbọ, ti wọn si wọ asọ dudu lati se ọfọ akọrin ẹmi naa.
Mọ̀lẹ́bí Olóògbé Fasoranti kéde ọjọ́ ìsìnkú lẹ́yìn tí èèkàn ọmọlẹ́yìn Awolowo náà jáde láyé lẹ́ni ọdún 100
Ọkunrin naa sọ pe eto isinku yoo waye laaarin ọjọ kẹrindinlogun si ọjọ kẹtadinlogun, oṣu Kejila, ọdun 2026.
Wọ́n yọ ìmáàmù nípò, wọ́n ló ń fi wáàsí polongo sáà kejì fún Tinubu
Iṣẹlẹ yii waye nipinlẹ Bauchi, Imaamu naa ni wọn pe orukọ rẹ ni Dahiru Abubakar.
Wo ìgbà mẹ́rin tí afẹ́fẹ́ òórùn burúkú ti ṣe àkóbá fún àwọn àkẹ́kọ̀ọ́ l'Ogun àti igbésẹ̀ ìjọba
Iṣẹlẹ yii ni yoo jẹ igba kẹrin iru rẹ to ṣẹlẹ laaarin ọdun 2026, ti ijọba ipinlẹ naa si ti n wa iyanju si i.
Ohun tí Mimiko, Seyi Makinde àtàwọn èèkàn míì sọ nípa Pa Fasoranti tó di olóògbé
Lara awọn to ṣabẹwo si awọn ẹbi baba Reuben Fasoranti ni gomina ipinlẹ Oyo, Seyi Makinde; gomina ipinlẹ nigba kan ri, Olusegun Mimiko; Deji Ilu Akure, Oba Aladetoyinbo; Ogunlade Aladelusi ati bẹẹ bẹẹ lọ
"Gbogbo èèyàn ló máa ń sọ pé ìyá mi rẹwà gidigidi"
Oṣere naa, to tun jẹ adari ere sọ fun BBC nipa boun pẹlu awọn aburo rẹ ṣe dagba, pẹlu awọn iriri rẹ bo ṣe n dagba.
'Ìgbà tí mo fi ọwọ́ kan itan mi tí mo rí ẹ̀jẹ̀ ni mo tó mọ̀ pé ọta àṣìta ìbọn ti bà mí' Broda Shaggi, ṣàlàyé ohun tó mú kó di àwátì lórí afẹ́fẹ́
Shaggi ni iṣẹlẹ naa mu ki ẹru ba oun nipa ọjọ ọla oun nigba ti oun wo o pe o ṣeeṣe ki awọn ololufẹ oun gbagbe oun latari bi wọn ko ṣe ri oun.
Bí arábìnrin tó kó Ebola wọ Nàìjíríà ṣe rìnrìnàjò afẹ́ lọ sí Uganda, àtàwọn ohun míràn tí a mọ̀ nípa àrùn Ebola àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà láti ọdún 2014
Ijọba orilẹede Uganda ti n fọnmu pe arabinrin naa ko wa si Uganda rara ati pe awọn ko ni arun Ebola lorilẹede wọn bi o tilẹ jẹ wi pe awọn orilẹede Africa yooku n sọ pe irọ ni.
South Africa kéde ẹ̀dínwó lórí epo bẹntiróòlù àti dísù, sọ̀rọ̀ lórí owó orí tẹ́tẹ́
Minisita feto iṣuna lorileede naa, Enoch Godongwana sọ pe aarin ọjọ kẹrin, oṣu Kọkanla, si ọjọ kinni, oṣu Kejila, ọdun 2026 ni ẹdinwo ọhun yoo fi waye.
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
"Àwọn tó yọ mí nípò ni yóò ṣì ṣàlàyé ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀" - Ọba ìlú Eselu sọ̀rọ̀
Nigba to n sọrọ, Kabiyesi sọ pe lotitọ loun ti gba iwe ti ijọba fi ranṣẹ soun, gẹgẹ bi jijawe gbeleẹ foun, ṣugbọn to loun ko ni ohunkohun lati sọ lori rẹ.
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí mẹ́fà lórí ikú Emir Ajagungbade l'Osun
Ọjọ kẹtala, oṣu Kẹsan-an, ọdun 2026 ni rogbodiyan to ṣeku pa Emir Ajagungbade waye ni agbegbe Mayfair to wa niluu Ile-Ife, ipinlẹ naa.
Wo bí o ṣe lè dá ẹni tó ní Ebola mọ̀, àti bí o ṣe lè dènà rẹ̀
Minisita feto ilera nilẹ Naijiria, Ọjọgbọn Muhammed Ali Pate lo fidi iroyin naa mulẹ fawọn akọroyin lọjọ Iṣẹgun, ogunjọ, oṣu Kẹwaa, ọdun 2026.
Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nipa àyẹ̀wò fóònù kí o tó rà á
Koodi ti NCC pe ni *315# ni awọn ọmọ Naijiria yoo tẹ sori foonu tuntun ti wọn ṣẹṣẹ fẹẹ ra lati le fidi rẹ mulẹ boya ojulowo ni foonu naa tabi ayederu.
DSS gbé àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nínú jíjí àwọn àgùnbánirọ̀ tó lọ láti Ibadan sí Imo lọ sílé ẹjọ́
Awọn afurasi naa nkoju ẹsun mẹta lati ori ijinigbe kan ninu awọn ohun ija oloro lọwọ.
"Dọ̀tun, ṣé mi ò ní kú ṣá?" Ìbéèrè tí Dele Giwa bi dókítà tí wọ́n gbé lọ sílé ìwòsàn rẹ̀ kó tó jáde láyé
Dokita naa ni pẹlu ọgbẹ ti oun ri lara rẹ, oun mọ pe o san ki Dele Giwa ku ju ko ye lọ.
Ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ lọ́wọ́, ẹ̀wọ̀n lẹ́sẹ̀, ọwọ́ òfin tẹ pásítọ̀ àti ìyàwó rẹ̀ tó ń so àwọn èèyàn mọ́lẹ̀ ní ìjọ wọn
Ọgba naa to wa labẹ akoso ile ijọsin agbegbe Mpumalanga, la gbọ pe awọn agbofinro ṣawari rẹ l'Ọjọbọ, ọsẹ to kọja yii.
"Ibọn ba mi ni igba aya lọjọ naa, titi di oni, mi o ri idajọ ododo gba", Ọdun mẹ́fà lẹ́yìn ìwọ́de EndSARS ṣé ìdájọ́ òdodo tí wáyé?
Iwọde naa jẹ ọkan gboogi lara awọn iwọde to milẹ titi julọ ni Naijiria ati kaakiri ilẹ adulawọ lasiko naa.
Ọ̀rọ̀ láàárín Toyin Abraham àti Funke Akindele tún súyọ lórí ayélujára, ohun tí a mọ̀ rèé
Ninu fọnran naa, iroyin ni Bisgold n bu Funke Akindele, ti wọn si fẹsun kan pe niṣe ni Toyin Abraham n rẹrin-in labẹlẹ bi Bisgold ṣe n bu Funke Akindele.
Táńkà epo Dísù rébọ́ sílẹ̀ láti orí afárá Otedola, iná sọ, èèyàn méjì jóná kọjá ààlà
Epo rọbii ti wọn n pe ni disu (diesel) ni wọn sọ pe ọkọ agbepo naa gbe, lasiko to ṣubu lulẹ naa.
Pásítọ̀ tó ṣokùnfá ikú ọ̀pọ̀ èèyàn ní Kenya jẹ̀bi ẹ̀sùn 191 tí wọ́n fi kàn án
Paul Mackenzie atawọn ọmọ ijọ rẹ mọkandinlọgbọn mii ni wọn fẹsun ipaniyan awọn ọmọde 191 kan.
Iléeṣẹ́ PoS kan tún ṣíwọ́ iṣẹ́ ní Nàìjíríà, ìdí rèé
Gẹgẹ bi ohun ti a gbọ, iye awọn to n lo POS Baxi le ni 90,000 kaakiri Naijiria.